Olatunbosun Adebesin

Biography: 18 year old Nigerian struggling to make ends meet

Olatunbosun Adebesin 's Profile


Olatunbosun Adebesin
Thursday 18 August 2022

OJÚLÓPÉSÍ

Ènìyàn n'sáré àtilà sùgbón, kìràkìtà ò dolà.

Omo adáríhurun n'sebí elédùà sùgbón, Oba òkè dáké.


Mákànjúolá òré èmi.

Ohun tí ò tó léèní yōō sékù lóla.


Ojúlópésí, ìyókù d'owó adániwáyé.

Sa ipáàre sùgbón má Sàáré àsápajúdé


Ànfàní ni'lé ayé jé, a ósì bi é bí o se ti lò.

Àkosílè èdá kīī tàsé, orí eni ló'ndire.


Má gbèrò kii tenì kejì bàjé, sebí oti mo.

Ìgbìnyànjú re, Olórun mò si


Bópé bóyá, ìyókù yōō dèrò.

Mádùúró, Márèwèsì, Ìyókù d'owó elúdùà

3
819 Views

Trending Now


Most Rated Poems


Recently Joined


FPG Feeds>